Online Bible

- Advertisements -




Joẹli 3:20 - Bibeli Mimọ

20 Ṣugbọn Juda yio joko titi lai, ati Jerusalemu lati iran de iran.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

20 Ṣugbọn àwọn eniyan yóo máa gbé ilẹ̀ Juda títí lae, wọn óo sì máa gbé ìlú Jerusalẹmu láti ìrandíran.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

20 Ṣùgbọ́n Juda yóò jẹ́ ibùgbé títí láé, àti Jerusalẹmu láti ìran dé ìran.

See the chapter Copy




Joẹli 3:20

Follow us:

Advertisements


Advertisements