Online Bible

- Advertisements -




Joẹli 3:19 - Bibeli Mimọ

19 Egipti yio di ahoro, Edomu yio si di aginju ahoro, nitori ìwa ipá si awọn ọmọ Juda, nitoriti nwọn ti ta ẹjẹ̀ alaiṣẹ̀ silẹ ni ilẹ wọn.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

19 “Ijipti yóo di aṣálẹ̀; Edomu yóo sì di ẹgàn, nítorí ìwà ipá tí wọ́n hù sí àwọn ará Juda, nítorí wọ́n ti pa àwọn aláìṣẹ̀ ní ilẹ̀ wọn.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

19 Ṣùgbọ́n Ejibiti yóò di ahoro, Edomu yóò sì di aṣálẹ̀ ahoro, nítorí ìwà ipá tí a hù sì àwọn ọmọ Juda, ní ilẹ̀ ẹni tí wọ́n ti ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀.

See the chapter Copy




Joẹli 3:19

Follow us:

Advertisements


Advertisements