Online Bible

- Advertisements -




Joẹli 3:13 - Bibeli Mimọ

13 Ẹ tẹ̀ doje bọ̀ ọ, nitori ikore pọ́n: ẹ wá, ẹ sọkalẹ; nitori ifunti kún, nitori awọn ọpọ́n kún rekọja, nitori ìwa-buburu wọn pọ̀.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

13 Ẹ ti dòjé bọ oko, nítorí àkókò ìkórè ti tó, ẹ lọ fún ọtí waini nítorí ibi ìfúntí ti kún. Ìkòkò ọtí ti kún àkúnwọ́sílẹ̀, nítorí ìkà wọ́n pọ̀.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

13 Ẹ tẹ dòjé bọ̀ ọ́, nítorí ìkórè pọ́n: ẹ wá, ẹ sọ̀kalẹ̀; nítorí ìfúntí kún, nítorí àwọn ọpọ́n kún àkúnwọ́sílẹ̀ nítorí ìwà búburú wọn pọ̀!”

See the chapter Copy




Joẹli 3:13

Follow us:

Advertisements


Advertisements