Online Bible

- Advertisements -




Esteri 9:30 - Bibeli Mimọ

30 O si fi iwe ranṣẹ si gbogbo awọn Ju, si ẹtadilãdoje ìgberiko ijọba Ahaswerusi, ọ̀rọ alafia ati otitọ.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

30 Wọ́n kọ ìwé sí gbogbo àwọn Juu ní gbogbo agbègbè mẹtẹẹtadinlaadoje (127) tí ó wà ninu ìjọba Ahasu-erusi. Ìwé náà kún fún ọ̀rọ̀ alaafia ati òtítọ́,

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

30 Mordekai sì kọ ìwé ránṣẹ́ sí gbogbo àwọn Júù, sí ìgbèríko mẹ́tà-dínláàádóje (127) ní ilẹ̀ ọba Ahaswerusi ní ọ̀rọ̀ àlàáfíà àti òtítọ́.

See the chapter Copy




Esteri 9:30

Follow us:

Advertisements


Advertisements