Online Bible

- Advertisements -




Esteri 2:4 - Bibeli Mimọ

4 Ki wundia na ti o ba wù ọba ki o jẹ ayaba ni ipò Faṣti. Nkan na si dara loju ọba, o si ṣe bẹ̃.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

4 kí wundia tí ó bá tẹ́ ọba lọ́rùn jù sì jẹ́ ayaba dípò Faṣiti.” Ìmọ̀ràn yìí dùn mọ́ ọba ninu, ó sì ṣe bẹ́ẹ̀.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

4 Nígbà naà kí ọmọbìnrin tí ó bá tẹ́ ọba lọ́rùn kí ó jẹ́ ayaba dípò Faṣti.” Ìmọ̀ràn yìí tẹ́ ọba lọ́rùn, ó sì tẹ̀lé e.

See the chapter Copy




Esteri 2:4

Follow us:

Advertisements


Advertisements