Esteri 1:9 - Bibeli Mimọ9 Faṣti ayaba sè àse pẹlu fun gbogbo awọn obinrin ni ile ọba ti iṣe ti Ahaswerusi. See the chapterYoruba Bible9 Ayaba Faṣiti pàápàá se àsè fún àwọn obinrin ní ààfin ọba Ahasu-erusi. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Ayaba Faṣti náà ṣe àsè fún àwọn obìnrin ní ààfin ọba Ahaswerusi. See the chapter |