Online Bible

- Advertisements -




Eksodu 6:16 - Bibeli Mimọ

16 Wọnyi si li orukọ awọn ọmọ Lefi ni iran wọn; Gerṣoni, ati Kohati, ati Merari: ọdún aiye Lefi si jẹ́ mẹtadilogoje.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

16 Lefi bí ọmọ mẹta: Geriṣoni, Kohati ati Merari; àwọn ni olórí àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi. Ọdún mẹtadinlogoje (137) ni Lefi gbé láyé.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

16 Ìwọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Lefi gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn: Gerṣoni, Kohati àti Merari. Lefi lo ẹ̀tàndínlógóje (137) ọdún láyé.

See the chapter Copy




Eksodu 6:16

Follow us:

Advertisements


Advertisements