Eksodu 4:29 - Bibeli Mimọ29 Mose ati Aaroni si lọ, nwọn si kó gbogbo àgba awọn ọmọ Israeli jọ: See the chapterYoruba Bible29 Mose ati Aaroni bá lọ sí Ijipti, wọ́n kó gbogbo àgbààgbà àwọn eniyan Israẹli jọ. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní29 Mose àti Aaroni pe gbogbo àwọn àgbàgbà Israẹli jọ. See the chapter |