Online Bible

- Advertisements -




Efesu 2:6 - Bibeli Mimọ

6 O si ti ji wa dide pẹlu rẹ̀, o si ti mu wa wa joko pẹlu rẹ̀ ninu awọn ọrun ninu Kristi Jesu:

See the chapter Copy

Yoruba Bible

6 Ọlọrun tún jí wa dìde pẹlu Kristi Jesu, ó wá fi wá jókòó pẹlu rẹ̀ lọ́run,

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 Ọlọ́run sì ti jí wa dìde pẹ̀lú Kristi, ó sì ti mú wa jókòó pẹ̀lú rẹ̀ nínú àwọn ọ̀run nínú Kristi Jesu.

See the chapter Copy




Efesu 2:6

Follow us:

Advertisements


Advertisements