Online Bible

- Advertisements -




Efesu 2:5 - Bibeli Mimọ

5 Nigbati awa tilẹ ti kú nitori irekọja wa, o sọ wa di ãye pẹlu Kristi (ore-ọfẹ li a ti fi gba nyin là).

See the chapter Copy

Yoruba Bible

5 ó sọ wá di alààyè pẹlu Kristi nígbà tí a ti di òkú ninu ìwàkíwà wa. Oore-ọ̀fẹ́ ni a fi gbà yín là.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

5 nígbà tí àwa tilẹ̀ ti kú nítorí ìrékọjá wa, ó sọ wá di ààyè pẹ̀lú Kristi, oore-ọ̀fẹ́ ni a ti fi gbà yín là.

See the chapter Copy




Efesu 2:5

Follow us:

Advertisements


Advertisements