Daniẹli 3:30 - Bibeli Mimọ30 Nigbana ni ọba gbé Ṣadraki, Meṣaki, ati Abednego leke ni igberiko Babeli. See the chapterYoruba Bible30 Ọba bá gbé Ṣadiraki, Meṣaki ati Abedinego sí ipò gíga ní ìgbèríko Babiloni. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní30 Nígbà náà ni ọba gbé Ṣadraki, Meṣaki àti Abednego ga ní gbogbo agbègbè ìjọba Babeli. See the chapter |