Daniẹli 2:37 - Bibeli Mimọ37 Iwọ ọba, li ọba awọn ọba: nitori Ọlọrun ọrun ti fi ijọba, agbara, ati ipá, ati ogo fun ọ. See the chapterYoruba Bible37 Kabiyesi, ìwọ ọba àwọn ọba ni Ọlọrun ọ̀run fún ní ìjọba, agbára, ipá ati ògo. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní37 Ìwọ ọba jẹ́ ọba àwọn ọba. Ọlọ́run ọ̀run ti fi ìjọba agbára, títóbi àti ògo fún ọ; See the chapter |