Online Bibel

- Annoncer -




Romu 1:9 - Yoruba Bible

9 Ọlọrun, tí mò ń fọkàn sìn bí mo ti ń waasu ìyìn rere Ọmọ rẹ̀, ni ẹlẹ́rìí mi pé mò ń ranti yín láì sinmi.

Se kapitlet Kopi

Bibeli Mimọ

9 Ọlọrun sá li ẹlẹri mi, ẹniti emi nfi ẹmi mi sìn ninu ihinrere Ọmọ rẹ̀, biotiṣepe li aisimi li emi nranti nyin nigbagbogbo ninu adura mi;

Se kapitlet Kopi

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

9 Ọlọ́run ṣá à ni ẹlẹ́rìí mi, ẹni tí èmí ń fi gbogbo ẹ̀mí mi sìn nínú ìhìnrere Ọmọ rẹ̀, bí ó ti ṣe pé ní àìsimi ni èmí ń rántí yín nígbà gbogbo nínú àdúrà mi

Se kapitlet Kopi




Romu 1:9

Følg os:

Annoncer


Annoncer