Ọbadiah 1:9 - Yoruba Bible9 Ìwọ ìlú Temani, ìbẹ̀rùbojo yóo dé bá àwọn akọni rẹ, gbogbo àwọn ọkunrin tí wọ́n wà ní òkè Esau ni a óo sì fi idà pa. Se kapitletBibeli Mimọ9 Awọn alagbara rẹ yio si bẹ̀ru, iwọ Temani, nitori ki a le ke olukuluku ti ori oke Esau kuro nitori ipania. Se kapitletBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 A ó ṣe ẹ̀rù ba àwọn jagunjagun rẹ, Ìwọ Temani, gbogbo àwọn tó wà ní orí òkè Esau ní a ó gé kúrò nínú ìpànìyàn náà. Se kapitlet |