Numeri 1:29 - Yoruba Bible29 jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlọgbọn ó lé irinwo (54,400). Se kapitletBibeli Mimọ29 Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Issakari, o jẹ́ ẹgbã mẹtadilọgbọ̀n o le irinwo. Se kapitletBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní29 Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Isakari jẹ́ ẹgbàá-mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ó-lé-irínwó (54,400). Se kapitlet |