Marku 1:37 - Yoruba Bible37 Nígbà tí wọ́n rí i, wọ́n wí fún un pé, “Gbogbo eniyan ní ń wá ọ.” Se kapitletBibeli Mimọ37 Nigbati nwọn si ri i, nwọn wi fun u pe, Gbogbo enia nwá ọ. Se kapitletBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní37 Nígbà tí wọ́n sì rí I, wọ́n sọ fún wí pé, “Gbogbo ènìyàn ń wá ọ!” Se kapitlet |