Johanu 1:4 - Yoruba Bible4 Òun ni orísun ìyè, ìyè náà ni ìmọ́lẹ̀ aráyé. Se kapitletBibeli Mimọ4 Ninu rẹ̀ ni ìye wà; ìye na si ni imọlẹ̀ araiye. Se kapitletBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní4 Nínú rẹ̀ ni ìyè wà, ìyè yìí náà sì ni ìmọ́lẹ̀ aráyé, Se kapitlet |