Eksodu 1:21 - Yoruba Bible21 Nítorí pé àwọn agbẹ̀bí náà bẹ̀rù Ọlọrun, ìdílé tiwọn náà pọ̀ síi. Se kapitletBibeli Mimọ21 O si ṣe, nitoriti awọn iyãgbà bẹ̀ru Ọlọrun, on si kọle fun wọn. Se kapitletBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní21 Nítorí pé àwọn agbẹ̀bí bẹ̀rù Ọlọ́run, Ọlọ́run sì fún wọn ni ìdílé tiwọn. Se kapitlet |