Online Bibel

- Annoncer -




Sekariah 1:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

9 Nígbà náà ni mo wí pé, “Kí ni wọ̀nyí olúwa mi?” Angẹli tí ń ba mi sọ̀rọ̀ sì wí fún mi pé, “Èmi ó fi ohun tí àwọn wọ̀nyí jẹ́ hàn ọ́.”

Se kapitlet Kopi

Yoruba Bible

9 Mo bá bèèrè pé, “OLUWA mi, kí ni ìtumọ̀ kinní wọnyi?” Angẹli tí ń bá mi sọ̀rọ̀ sì dáhùn pé, “N óo sọ ìtumọ̀ wọn fún ọ.”

Se kapitlet Kopi

Bibeli Mimọ

9 Nigbana ni mo wipe, Kini wọnyi oluwa mi? Angeli ti mba mi sọ̀rọ si wi fun mi pe, emi o fi ohun ti wọnyi jẹ hàn ọ.

Se kapitlet Kopi




Sekariah 1:9

Følg os:

Annoncer


Annoncer