Online Bibel

- Annoncer -




Romu 1:8 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

8 Ní àkọ́kọ́, mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nípasẹ̀ Jesu Kristi fún gbogbo yín, nítorí a ń ròyìn ìgbàgbọ́ yin káàkiri gbogbo ayé.

Se kapitlet Kopi

Yoruba Bible

8 Kí á tó máa bá ọ̀rọ̀ wa lọ, mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun mi nípasẹ̀ Jesu Kristi nítorí gbogbo yín; nítorí àwọn eniyan ń ròyìn igbagbọ yín ní gbogbo ayé.

Se kapitlet Kopi

Bibeli Mimọ

8 Mo kọ́ dupẹ na lọwọ Ọlọrun mi nipasẹ Jesu Kristi nitori gbogbo nyin, nitoripe a nròhin igbagbọ́ nyin yi gbogbo aiye ká.

Se kapitlet Kopi




Romu 1:8

Følg os:

Annoncer


Annoncer