Oniwaasu 1:2 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní2 “Asán inú asán!” oníwàásù náà wí pé, “Asán inú asán! Gbogbo rẹ̀ asán ni.” Se kapitletYoruba Bible2 Asán ninu asán, bí ọ̀jọ̀gbọ́n ti wí, asán ninu asán, gbogbo rẹ̀ asán ni. Se kapitletBibeli Mimọ2 Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo rẹ̀ asan ni! Se kapitlet |