Online Bibel

- Annoncer -




Marku 1:32 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

32 Nígbà tí ó di àṣálẹ́, tí oòrùn wọ̀, wọ́n gbé gbogbo àwọn aláìsàn àti àwọn tó ni ẹ̀mí àìmọ́ tọ̀ ọ́ wá.

Se kapitlet Kopi

Yoruba Bible

32 Nígbà tí ó di ìrọ̀lẹ́, tí oòrùn wọ̀, àwọn eniyan bẹ̀rẹ̀ sí gbé gbogbo àwọn tí ara wọn kò dá ati àwọn tí wọ́n ní ẹ̀mí èṣù wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀.

Se kapitlet Kopi

Bibeli Mimọ

32 Nigbati o di aṣalẹ, ti õrun wọ̀, nwọn gbe gbogbo awọn alaìsan, ati awọn ti o li ẹmi i èṣu tọ̀ ọ wá.

Se kapitlet Kopi




Marku 1:32

Følg os:

Annoncer


Annoncer