Online Bibel

- Annoncer -




Marku 1:29 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

29 Nígbà tí wọn sì jáde kúrò nínú Sinagọgu, wọ́n lọ pẹ̀lú Jakọbu àti Johanu sí ilé Simoni àti Anderu.

Se kapitlet Kopi

Yoruba Bible

29 Bí wọ́n ti jáde kúrò ninu ilé ìpàdé, Jesu pẹlu Jakọbu ati Johanu lọ sí ilé Simoni ati Anderu.

Se kapitlet Kopi

Bibeli Mimọ

29 Nigbati nwọn si jade kuro ninu sinagogu, lojukanna nwọn wọ̀ ile Simoni ati Anderu, pẹlu Jakọbu ati Johanu.

Se kapitlet Kopi




Marku 1:29

Følg os:

Annoncer


Annoncer