Online Bibel

- Annoncer -




Luku 1:76 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

76 “Àti ìwọ, ọmọ mi, wòlíì Ọ̀gá-ògo jùlọ ni a ó máa pè ọ́: nítorí ìwọ ni yóò ṣáájú Olúwa láti tún ọ̀nà rẹ̀ ṣe;

Se kapitlet Kopi

Yoruba Bible

76 “Ìwọ, ọmọ mi, wolii Ọ̀gá Ògo ni a óo máa pè ọ́, nítorí ìwọ ni yóo ṣáájú Oluwa láti palẹ̀ mọ́ dè é,

Se kapitlet Kopi

Bibeli Mimọ

76 Ati iwọ, ọmọ, woli Ọgá-ogo li a o ma pè ọ: nitori iwọ ni yio ṣaju Oluwa lati tún ọ̀na rẹ̀ ṣe;

Se kapitlet Kopi




Luku 1:76

Følg os:

Annoncer


Annoncer