Online Bibel

- Annoncer -




Luku 1:48 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

48 Nítorí tí ó ṣíjú wo ìwà ìrẹ̀lẹ̀ ọmọbìnrin ọ̀dọ̀ rẹ̀: Sá wò ó. Láti ìsinsin yìí lọ gbogbo ìran ènìyàn ni yóò máa pè mí ní alábùkún fún.

Se kapitlet Kopi

Yoruba Bible

48 nítorí ó ti bojúwo ipò ìrẹ̀lẹ̀ iranṣẹbinrin rẹ̀. Wò ó! Láti ìgbà yìí lọ gbogbo ìran ni yóo máa pè mí ní olóríire.

Se kapitlet Kopi

Bibeli Mimọ

48 Nitoriti o ṣijuwò ìwa irẹlẹ ọmọbinrin ọdọ rẹ̀: sá wò o, lati isisiyi lọ gbogbo iran enia ni yio ma pè mi li alabukunfun.

Se kapitlet Kopi




Luku 1:48

Følg os:

Annoncer


Annoncer