Online Bibel

- Annoncer -




Luku 1:36 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

36 Sì kíyèsi i, Elisabeti ìbátan rẹ náà yóò sì ní ọmọkùnrin kan ní ògbólógbòó rẹ̀. Èyí sì ni oṣù kẹfà fún ẹni tí à ń pè ní àgàn.

Se kapitlet Kopi

Yoruba Bible

36 Ati pé Elisabẹti, ìbátan rẹ náà ti lóyún ọmọkunrin kan ní ìgbà ogbó rẹ̀. Ẹni tí wọ́n ti ń pè ní àgàn rí sì ti di aboyún oṣù mẹfa.

Se kapitlet Kopi

Bibeli Mimọ

36 Si kiyesi i, Elisabeti ibatan rẹ, on pẹlu si lóyun ọmọkunrin kan li ogbologbo rẹ̀: eyi si li oṣu kẹfa fun ẹniti a npè li agàn.

Se kapitlet Kopi




Luku 1:36

Følg os:

Annoncer


Annoncer