Luku 1:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 Òun ó sì yí ènìyàn púpọ̀ padà nínú àwọn ọmọ Israẹli sí Olúwa Ọlọ́run wọn. Se kapitletYoruba Bible16 ọpọlọpọ àwọn ọmọ Israẹli ni yóo sì yipada sí Oluwa Ọlọrun wọn. Se kapitletBibeli Mimọ16 On o si pa pipọ da ninu awọn ọmọ Israeli si Oluwa Ọlọrun wọn. Se kapitlet |