Online Bibel

- Annoncer -




Joẹli 1:20 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

20 Àwọn ẹranko igbó gbé ojú sókè sí ọ pẹ̀lú: nítorí tí àwọn ìṣàn omi gbẹ, iná sí ti jó àwọn pápá oko aginjù run.

Se kapitlet Kopi

Yoruba Bible

20 Àwọn ẹranko ìgbẹ́ pàápàá ń kígbe sí ọ, Ọlọrun, nítorí gbogbo àwọn odò ti gbẹ tán, àwọn pápá oko sì ti jóná.

Se kapitlet Kopi

Bibeli Mimọ

20 Awọn ẹranko igbẹ gbé oju soke si ọ pẹlu: nitoriti awọn iṣàn omi gbẹ, iná si ti jó awọn pápa oko aginju run.

Se kapitlet Kopi




Joẹli 1:20

Følg os:

Annoncer


Annoncer