Eksodu 1:21 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní21 Nítorí pé àwọn agbẹ̀bí bẹ̀rù Ọlọ́run, Ọlọ́run sì fún wọn ni ìdílé tiwọn. Se kapitletYoruba Bible21 Nítorí pé àwọn agbẹ̀bí náà bẹ̀rù Ọlọrun, ìdílé tiwọn náà pọ̀ síi. Se kapitletBibeli Mimọ21 O si ṣe, nitoriti awọn iyãgbà bẹ̀ru Ọlọrun, on si kọle fun wọn. Se kapitlet |