Online Bibel

- Annoncer -




Efesu 1:17 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

17 Mo sì ń béèrè nígbà gbogbo pé kí Ọlọ́run Jesu Kristi Olúwa wa, Baba ògo, lè fún yín ni Ẹ̀mí nípa ti ọgbọ́n àti ti ìfihàn kí ẹ̀yin kí ó tún lè mọ̀ ọ́n sí i.

Se kapitlet Kopi

Yoruba Bible

17 Mò ń gbadura pé kí Ọlọrun, Baba Oluwa wa Jesu Kristi, Baba ológo, lè fun yín ní ẹ̀mí ọgbọ́n, kí ó sì jẹ́ kí ẹ ní ìmọ̀ tí ó kún nípa òun alára.

Se kapitlet Kopi

Bibeli Mimọ

17 Pe ki Ọlọrun Jesu Kristi Oluwa wa, Baba ogo, le fun nyin li Ẹmi nipa ti ọgbọ́n ati ti ifihan ninu ìmọ rẹ̀:

Se kapitlet Kopi




Efesu 1:17

Følg os:

Annoncer


Annoncer