Online Bibel

- Annoncer -




Numeri 1:45 - Bibeli Mimọ

45 Bẹ̃ni gbogbo awọn ti a kà ninu awọn ọmọ Israeli, nipa ile baba wọn, lati ẹni ogún ọdún lọ ati jù bẹ̃ lọ, gbogbo awọn ti o le jade lọ si ogun ni Israeli;

Se kapitlet Kopi

Yoruba Bible

45 Àròpọ̀ iye àwọn ọmọ Israẹli, ní ìdílé-ìdílé, láti ẹni ogún ọdún sókè, àwọn tí wọ́n lè lọ sójú ogun,

Se kapitlet Kopi

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

45 Gbogbo ọmọkùnrin Israẹli tó jẹ́ ọmọ ogún ọdún (20) sókè, tó sì lè lọ sójú ogun ni wọ́n kà gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.

Se kapitlet Kopi




Numeri 1:45

Følg os:

Annoncer


Annoncer