Numeri 1:37 - Bibeli Mimọ37 Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Benjamini, o jẹ́ ẹgba mẹtadilogun o le egbeje. Se kapitletYoruba Bible37 jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlogun ó lé egbeje (35,400). Se kapitletBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní37 Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Benjamini jẹ́ ẹgbàá-mẹ́tà-dínlógún ó-lé-egbèje (35,400). Se kapitlet |