Marku 1:18 - Bibeli Mimọ18 Lojukanna nwọn si fi àwọn wọn silẹ, nwọn si tọ̀ ọ lẹhin. Se kapitletYoruba Bible18 Lẹ́sẹ̀ kan náà wọ́n bá fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n ń tẹ̀lé e. Se kapitletBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní18 Ní kánkán wọ́n fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n sì tọ̀ Ọ́ lẹ́yìn. Se kapitlet |