Online Bibel

- Annoncer -




Esra 1:9 - Bibeli Mimọ

9 Iye wọn si li eyi: ọgbọn awo-pọ̀kọ wura, ẹgbẹrun awo-pọ̀kọ fadaka, ọbẹ mọkandilọgbọn,

Se kapitlet Kopi

Yoruba Bible

9 Iye àwọn nǹkan náà nìyí: Ẹgbẹrun kan (1,000) àwo wúrà, ẹgbẹrun kan (1,000) àwo fadaka, àwo turari mọkandinlọgbọn;

Se kapitlet Kopi

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

9 Èyí ni iye wọn: Ọgbọ̀n àwo wúrà 30 Ẹgbẹ̀rún àwo fàdákà 1,000 Àwo ìrúbọ fàdákà mọ́kàn-dínlọ́gbọ̀n 29

Se kapitlet Kopi




Esra 1:9

Følg os:

Annoncer


Annoncer