Romu 1:2 - Yoruba Bible2 Bí a bá wo inú Ìwé Mímọ́, a óo rí i pé àwọn wolii ti kéde ìyìn rere náà tẹ́lẹ̀ rí. Viz kapitolaBibeli Mimọ2 (Ti o ti ṣe ileri tẹlẹ rí ninu iwe-mimọ́, lati ọwọ awọn woli rẹ̀), Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní2 ìhìnrere tí ó ti ṣe ìlérí tẹ́lẹ̀ rí láti ẹnu àwọn wòlíì rẹ̀ nínú ìwé Mímọ́. Viz kapitola |