Ọbadiah 1:8 - Yoruba Bible8 “Ní ọjọ́ náà, ni n óo pa àwọn ọlọ́gbọ́n run ní Edomu, òye wọn yóo sì di òfo ní òkè Esau. Viz kapitolaBibeli Mimọ8 Oluwa wipe, li ọjọ na ki emi o run awọn ọlọgbọn kuro ni Edomu, ati imoye kuro li oke Esau? Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní8 Olúwa wí pé, “Ní ọjọ́ náà, Èmi kì yóò ha pa àwọn ọlọ́gbọ́n Edomu run, àti àwọn amòye run kúrò ní òkè Esau? Viz kapitola |