Online Bible

- Reklamy -




Ọbadiah 1:21 - Yoruba Bible

21 Àwọn olùgbàlà yóo lọ láti Sioni, wọn yóo jọba lórí òkè Edomu; ìjọba náà yóo sì jẹ́ ti OLUWA.”

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

21 Awọn olugbala yio si goke Sioni wá lati ṣe idajọ oke Esau; ijọba na yio si jẹ ti Oluwa.

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

21 Àwọn tó ń gba ni là yóò sì gòkè Sioni wá láti jẹ ọba lé orí àwọn òkè Esau. Ìjọba náà yóò sì jẹ́ ti Olúwa.

Viz kapitola kopírovat




Ọbadiah 1:21

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy