Online Bible

- Reklamy -




Ọbadiah 1:17 - Yoruba Bible

17 “Ṣugbọn ní òkè Sioni ni àwọn tí wọ́n bá sá àsálà yóo máa gbé, yóo sì jẹ́ òkè mímọ́; àwọn ọmọ Jakọbu yóo gba ohun ìní wọn pada.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

17 Ṣugbọn igbala yio wà lori oke Sioni, yio si jẹ mimọ́, awọn ara ile Jakobu yio si ni ini wọn.

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

17 Ṣùgbọ́n ìgbàlà yóò wà lórí òkè Sioni Wọn yóò sì jẹ́ mímọ́ àti ilé Jakọbu yóò sì ní ìní wọn

Viz kapitola kopírovat




Ọbadiah 1:17

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy