Online Bible

- Reklamy -




Ọbadiah 1:16 - Yoruba Bible

16 Ẹ̀yin eniyan mi, bí ẹ ti jìyà ní òkè mímọ́ mi, bẹ́ẹ̀ ni gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè náà yóo jìyà; wọn óo jìyà yóo tẹ́ wọn lọ́rùn, wọn yóo sì wà gẹ́gẹ́ bí ẹni pé wọn kò sí rí.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

16 Nitori bi ẹnyin ti mu lori oke mimọ́ mi, bẹ̃ni gbogbo awọn keferi yio ma mu titi, nitõtọ, nwọn o mu, nwọn o si gbemì, nwọn o si wà bi ẹnipe nwọn kò ti si.

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

16 Gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀ ṣe mu lórí òkè mímọ́ mi bẹ́ẹ̀ ni gbogbo kèfèrí yóò máa mu títí Wọn yóò mu wọn yóò sì mu àmutẹ́rùn wọn yóò sì wà bí ẹni pé wọn kò wà rí

Viz kapitola kopírovat




Ọbadiah 1:16

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy