Online Bible

- Reklamy -




Ọbadiah 1:15 - Yoruba Bible

15 “Ọjọ́ ìdájọ́ OLUWA fẹ́rẹ̀ dé sórí àwọn orílẹ̀-èdè; a óo san án fún ọ, gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ. Ohun tí o bá ṣe, yóo pada sí orí ara rẹ.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

15 Nitori ọjọ Oluwa kù si dẹdẹ sori gbogbo awọn keferi: bi iwọ ti ṣe, bẹ̃li a o si ṣe si ọ: ẹsan rẹ yio si yipada sori ara rẹ.

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

15 “Nítorí ọjọ́ Olúwa súnmọ́ etílé lórí gbogbo àwọn kèfèrí. Bí ìwọ ti ṣe, bẹ́ẹ̀ ni a ó ṣe sí ìwọ náà; ẹ̀san rẹ yóò sì yípadà sí orí ara rẹ.

Viz kapitola kopírovat




Ọbadiah 1:15

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy