Online Bible

- Reklamy -




Ọbadiah 1:14 - Yoruba Bible

14 O kì bá tí dúró sí oríta, kí o máa mú àwọn tí wọn ń gbìyànjú láti sá àsálà; o kì bá tí fà wọ́n lé àwọn ọ̀tá wọn lọ́wọ́ ní ọjọ́ ìpọ́njú wọn.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

14 Bẹ̃ni iwọ kì ba ti duro ni ikorita lati ké awọn tirẹ̀ ti o ti salà kuro; bẹ̃ni iwọ kì ba ti sé awọn tirẹ̀ ti o kù li ọjọ wahala mọ.

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

14 Ìwọ kì bá tí dúró ní ìkóríta ọ̀nà láti ké àwọn tirẹ̀ tó ti sálà kúrò. Ìwọ kì bá tí fa àwọn tó ṣẹ́kù nínú wọn lélẹ̀ ní ọjọ́ wàhálà wọn.

Viz kapitola kopírovat




Ọbadiah 1:14

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy