Ọbadiah 1:12 - Yoruba Bible12 O kì bá tí fi arakunrin rẹ ṣẹ̀sín ní ọjọ́ ìpọ́njú rẹ̀; o kì bá tí jẹ́ kí inú rẹ dùn, ní ọjọ́ ìparun àwọn eniyan Juda; o kì bá tí fọ́nnu ní ọjọ́ ìbànújẹ́ wọn. Viz kapitolaBibeli Mimọ12 Ṣugbọn iwọ kì ba ti ṣiju wo ọjọ arakunrin rẹ ni ọjọ ti on di ajeji; bẹ̃ni iwọ kì ba ti yọ̀ lori awọn ọmọ Juda ni ọjọ iparun wọn; bẹ̃ni iwọ kì ba ti sọ̀rọ irera ni ọjọ wahala. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Ìwọ kì bá tí fi ojú kéré arákùnrin rẹ, ní àkókò ìbànújẹ́ rẹ̀ ìwọ kì bá tí yọ̀ lórí àwọn ọmọ Juda, ní ọjọ́ ìparun wọn ìwọ kì bá tí gbéraga púpọ̀ ní ọjọ́ wàhálà wọn. Viz kapitola |