Ọbadiah 1:10 - Yoruba Bible10 “Nítorí ìwà ìkà tí ẹ hù sí àwọn ọmọ Israẹli, arakunrin yín, ojú yóo tì yín a óo sì pa yín run títí lae. Viz kapitolaBibeli Mimọ10 Nitori ìwa-ipa si Jakobu arakunrin rẹ itiju yio bò ọ, a o si ke ọ kuro titi lai. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní10 Nítorí ìwà ipá sí Jakọbu arákùnrin rẹ, ìtìjú yóò bò ọ, a ó sì pa ọ run títí láé. Viz kapitola |