Ọbadiah 1:1 - Yoruba Bible1 Ìran tí Ọbadaya rí nìyí, OLUWA Ọlọrun sọ nípa Edomu pé: A ti gbọ́ ìròyìn láti ọ̀dọ̀ OLUWA, ó sì ti rán iranṣẹ rẹ̀ sí àwọn orílẹ̀-èdè pé: “Ẹ múra, ẹ jẹ́ kí á lọ bá Edomu jagun!” Viz kapitolaBibeli Mimọ1 IRAN ti Obadiah. Bayi ni Oluwa Ọlọrun wi niti Edomu; Awa ti gbọ́ ihìn kan lati ọdọ Oluwa wá, a si ti rán ikọ̀ kan si ãrin awọn keferi, Ẹ dide, ẹ si jẹ ki a dide ogun si i. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní1 Ìran ti Ọbadiah. Èyí ni Olúwa Olódùmarè wí nípa Edomu. Àwa ti gbọ́ ohùn kan láti ọ̀dọ̀ Olúwa wá: A sì ti rán ikọ̀ kan sí gbogbo kèfèrí láti sọ pé, “Ẹ dìde, ẹ jẹ́ kí a dìde ogun sí i.” Viz kapitola |