Numeri 1:25 - Yoruba Bible25 jẹ́ ẹgbaa mejilelogun ó lé aadọta lé ní ẹgbẹjọ (45,650). Viz kapitolaBibeli Mimọ25 Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Gadi, o jẹ́ ẹgba mejilelogun o le ãdọtalelẹgbẹjọ. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní25 Iye àwọn tí a kà nínú ẹ̀yà Gadi jẹ́ ẹgbàá-méjìlélógún ó-lé-àádọ́ta-lé-lẹ́gbẹ̀jọ (45,650). Viz kapitola |