Nehemiah 1:1 - Yoruba Bible1 Ìtàn Nehemaya ọmọ Hakalaya. Ní oṣù Kisilefi, ní ogún ọdún tí Atasasesi jọba ní ilẹ̀ Pasia, mo wà ní Susa tíí ṣe olú-ìlú ilẹ̀ náà, Viz kapitolaBibeli Mimọ1 Ọ̀RỌ Nehemiah ọmọ Hakaliah. O si ṣe ninu oṣu Kisleu, ni ogún ọdun, nigba tí mo wà ni Ṣuṣani ãfin. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní1 Ọ̀rọ̀ Nehemiah ọmọ Hakaliah: Ní oṣù Kisleu ní ogún ọdún (ìjọba Ahaswerusi ọba Persia) nígbà tí mo wà ní ààfin Susa, Viz kapitola |