Online Bible

- Reklamy -




Mika 1:12 - Yoruba Bible

12 Àwọn ará Marotu ń retí ire pẹlu gbogbo ọkàn wọn, nítorí pé ibi ti dé sí bodè Jerusalẹmu láti ọ̀dọ̀ OLUWA.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

12 Nitori ara Maroti nreti ire, ṣugbọn ibi sọkalẹ ti ọdọ Oluwa wá si ẹnu bode Jerusalemu.

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

12 Nítorí àwọn tí ó ń gbé ni Marati ń retí ìre, Ṣùgbọ́n ibi sọ̀kalẹ̀ ti ọ̀dọ̀ Olúwa wá sí ẹnu-bodè Jerusalẹmu.

Viz kapitola kopírovat




Mika 1:12

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy