Isaiah 1:29 - Yoruba Bible29 Ojú yóo tì yín, fún àwọn igi Oaku tí ẹ nífẹ̀ẹ́ láti máa bọ. Ojú yóo sì tì yín fún àwọn ọgbà oriṣa tí ẹ yàn. Viz kapitolaBibeli Mimọ29 Nitoriti oju yio tì wọn niti igi-nla ti ẹnyin ti fẹ, a o si dãmu nyin niti ọgbà ti ẹnyin ti yàn. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní29 “Ojú yóò tì yín nítorí igi óákù mímọ́ èyí tí ẹ ní inú dídùn sí, a ó kàn yín lábùkù nítorí àwọn ọgbà yìí tí ẹ ti yàn fúnrayín. Viz kapitola |