Online Bible

- Reklamy -




Isaiah 1:24 - Yoruba Bible

24 Nítorí náà, OLUWA àwọn ọmọ ogun, Alágbára Israẹli ní: “N óo bínú sí àwọn ọ̀tá mi, n óo sì gbẹ̀san lára àwọn tí ó kórìíra mi.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

24 Nitorina Oluwa, Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ẹni alagbara Israeli, wipe, A, emi o fi aiya balẹ niti awọn ọtá mi, emi o si gbẹ̀san lara awọn ọtá mi.

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

24 Nítorí náà ni Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun, alágbára kan ṣoṣo tí Israẹli sọ wí pé: “Á à! Èmi yóò ní ìfọ̀kànbalẹ̀ lórí àwọn ọ̀tá mi n ó sì gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá mi.

Viz kapitola kopírovat




Isaiah 1:24

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy