Online Bible

- Reklamy -




Isaiah 1:12 - Yoruba Bible

12 Nígbà tí ẹ bá wá jọ́sìn níwájú mi, ta ló bẹ̀ yín ní gbogbo gìrìgìrì lásán, tí ẹ̀ ń dà ninu àgbàlá mi.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

12 Nigbati ẹnyin wá lati fi ara hàn niwaju mi, tali o bere eyi lọwọ nyin, lati tẹ̀ agbalá mi?

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

12 Nígbà tí ẹ wá farahàn níwájú mi, ta ni ó béèrè èyí lọ́wọ́ yín, Gìrì gìrì ẹsẹ̀ nínú àgbàlá mi?

Viz kapitola kopírovat




Isaiah 1:12

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy